Àìsáyà 37:32 BMY

32 Nítorí láti Jérúsálẹ́mù ni àwọn àṣẹ́kù yóò ti wá,àti láti òkè Ṣíhónì ni ikọ̀ àwọn tí ó sálà.Ìtara Olúwa àwọn ọmọ-ogun ni yóò mú èyí ṣẹ.

Ka pipe ipin Àìsáyà 37

Wo Àìsáyà 37:32 ni o tọ