Àìsáyà 38:11 BMY

11 Èmi wí pé, “Èmi kì yóò lè tún rí Olúwa mọ́,àni Olúwa, ní ilẹ̀ àwọn alààyè;èmi kì yóò lè síjú wo ọmọnìyàn mọ́,tàbí kí n wà pẹ̀lú àwọn tí ó sì ńgbe orílẹ̀ ayé báyìí.

Ka pipe ipin Àìsáyà 38

Wo Àìsáyà 38:11 ni o tọ