Àìsáyà 39:1 BMY

1 Ní àkókò náà ni Méródákì-Báládánì ọmọ Báládánì ọba Bábílónì fi ìwé àti ẹ̀bùn ránṣẹ́ sí Heṣekáyà, nítorí ó gbọ́ pé ó ṣàìsàn ó sì gbádùn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 39

Wo Àìsáyà 39:1 ni o tọ