Àìsáyà 4:2 BMY

2 Ní ọjọ́ náà, ẹ̀ka Olúwa yóò ní ẹwà àti ogo, èso ilẹ̀ náà yóò sì jẹ́ ìgbéraga àti ògo àwọn ti ó sálà ní Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin Àìsáyà 4

Wo Àìsáyà 4:2 ni o tọ