Àìsáyà 40:19 BMY

19 Ní ti ère, oníṣọ̀nà ni ó dà á,ti alágbẹ̀dẹ wúrà sì fi wúrà bò ótí a sì ṣe ẹ̀wọ̀n ọ̀nà sílífà fún un.

Ka pipe ipin Àìsáyà 40

Wo Àìsáyà 40:19 ni o tọ