Àìsáyà 40:27 BMY

27 Èéṣe tí o fi sọ, Ìwọ Jákọ́bùàti tí o ṣàròyé, Ìwọ Ísírẹ́lì;“Ọ̀nà mi pamọ́ níwájú Olúwa;ìṣe mi ni a kò kọbi ara síláti ọwọ́ Ọlọ́run mi”?

Ka pipe ipin Àìsáyà 40

Wo Àìsáyà 40:27 ni o tọ