Àìsáyà 40:31 BMY

31 Ṣùgbọ́n àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀lé Olúwayóò tún agbára wọn ṣe.Wọn yóò fìyẹ́ fò lókè bí idì;wọn yóò ṣáré àárẹ̀ kò ní mú wọn,wọn yóò rìn òòyì kò ní kọ́ wọn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 40

Wo Àìsáyà 40:31 ni o tọ