Àìsáyà 40:4 BMY

4 Gbogbo àfonífojì ni a ó gbé ṣókè,gbogbo òkè ńlá àti òkè kékeré ni yóò di pẹ̀tẹ́lẹ̀;wíwọ́ ni a ó sọ di títọ́ àtiọ̀nà pálapàla ni a yóò sọ di títẹ́jú pẹrẹṣẹ,

Ka pipe ipin Àìsáyà 40

Wo Àìsáyà 40:4 ni o tọ