Àìsáyà 41:27 BMY

27 Èmi ni ẹni àkọ́kọ́ tí ó sọ fún Ṣíhóńì pé,‘Wò ó, àwọn nìyìí!’Mo fún Jérúsálẹ́mù ní ìránṣẹ́ ìhìn ayọ̀ kan.

Ka pipe ipin Àìsáyà 41

Wo Àìsáyà 41:27 ni o tọ