Àìsáyà 41:4 BMY

4 Ta ni ó ti ṣe èyí tí ó sì ti jẹ́ kí ó wáyé,tí ó ti pe ìran-ìran láti àtètèkọ́ṣe?Èmi Olúwa pẹ̀lú ẹnì kìn-ín-ní wọnàti ẹni tí ó gbẹ̀yìn, Èmi ni ẹni náà.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 41

Wo Àìsáyà 41:4 ni o tọ