Àìsáyà 42:6 BMY

6 “Èmi, Olúwa, ti pè ọ́ ní òdodo;Èmi yóò di ọwọ́ọ̀ rẹ mú.Èmi yóò pa ọ́ mọ́, n ó sì ṣe ọ́láti jẹ́ májẹ̀mú fún àwọn ènìyànàti ìmọ́lẹ̀ fún àwọn aláìkọlà

Ka pipe ipin Àìsáyà 42

Wo Àìsáyà 42:6 ni o tọ