Àìsáyà 42:8 BMY

8 “Èmi ni Olúwa; orúkọ mi nìyìí!Èmi kì yóò fi ògo mi fún ẹlòmìíràntàbí ìyìn mi fún ère-òrìṣà.

Ka pipe ipin Àìsáyà 42

Wo Àìsáyà 42:8 ni o tọ