Àìsáyà 43:25 BMY

25 “Èmi, àní Èmi, Èmi ni ẹni tí ó wẹ àwọnàìṣedédé rẹ nù, nítorí èmi fún ara mi,tí n kò sì rántí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ mọ́.

Ka pipe ipin Àìsáyà 43

Wo Àìsáyà 43:25 ni o tọ