Àìsáyà 44:14 BMY

14 Ó gé igi kédárì lulẹ̀,tàbí bóyá ó mú Ṣípírẹ́sì tàbí óákù.Ó jẹ́ kí ó dàgbà láàrin àwọn igi inú igbó,ó sì le gbin igi páínì, èyí tí òjò mú kí ó dàgbà.

Ka pipe ipin Àìsáyà 44

Wo Àìsáyà 44:14 ni o tọ