Àìsáyà 44:17 BMY

17 Nínú èyí tí ó kù ni ó ti ṣe òrìṣà, ère rẹ̀;ó forí balẹ̀ fún un, ó sì sìn ín.Ó gbàdúrà sí i, ó wí pé,“Gbà mí, ìwọ ni Ọlọ́run mi.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 44

Wo Àìsáyà 44:17 ni o tọ