Àìsáyà 45:1 BMY

1 Èyí ni ohun tí Olúwa sọ fún ẹni òróró rẹ̀,sí Kírúsì, ọwọ́ ọ̀tún ẹni tí mo dì múláti dojú àwọn orílẹ̀ èdè bolẹ̀ níwájú rẹ̀àti láti gba ohun ìjà àwọn ọba lọ́wọ́ wọn,láti sí àwọn ìlẹ̀kùn níwájú rẹ̀tí ó fi jẹ́ pé a kì yóò ti àwọn ẹnu-ọ̀nà.

Ka pipe ipin Àìsáyà 45

Wo Àìsáyà 45:1 ni o tọ