Àìsáyà 46:4 BMY

4 Pẹ̀lúpẹ̀lú sí àwọn arúgbó àti ewú oríi yínÈmi ni ẹni náà, Èmi ni ẹni tí yóò gbé ọ ró.Èmi ti mọ ọ́, èmi yóò sì gbé ọ;Èmi yóò dì ọ́ mú èmi ó sì gbà ọ́ sílẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 46

Wo Àìsáyà 46:4 ni o tọ