Àìsáyà 47:3 BMY

3 Ìhòòhò rẹ ni a ó fihàn sítaàti ìtìjú rẹ ni a ó sí sílẹ̀.Èmi yóò sì gba ẹ̀ṣan;Èmi kì yóò sì dá ẹnìkan sí.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 47

Wo Àìsáyà 47:3 ni o tọ