Àìsáyà 48:19 BMY

19 Àwọn ọmọ rẹ ìbá ti dàbí i yanrìn,àwọn ọmọ yín bí i horo ọkà tí a kò lè kà tán;orúkọ wọn ni a kì yóò ké kúròtàbí kí a pa wọ́n run níwájú mi.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 48

Wo Àìsáyà 48:19 ni o tọ