Àìsáyà 49:9 BMY

9 Láti sọ fún àwọn ìgbèkùn pé, ‘Ẹ jáde wá’àti fún àwọn tí ó wà nínú òkùnkùn pé, ‘Ẹ gba òmìnira!’“Wọn yóò máa jẹ ní ẹ̀bá ọ̀nààti koríko tútù lórí òkè aláìléwéko.

Ka pipe ipin Àìsáyà 49

Wo Àìsáyà 49:9 ni o tọ