Àìsáyà 5:14 BMY

14 Nítorí náà isà òkú ti ń dátọ́mì gidigidi,ó sì ti ya ẹnu rẹ̀ sílẹ̀ gbagada,nínú rẹ̀ ni àwọn gbajúmọ̀ àti mẹ̀kúnnù yóò sọ̀kalẹ̀ sípẹ̀lú ọlá àti ògo wọn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 5

Wo Àìsáyà 5:14 ni o tọ