Àìsáyà 5:16 BMY

16 Ṣùgbọ́n Olúwa àwọn ọmọ-ogun ni a ó gbéga nípa ẹ̀tọ́ rẹ̀,Ọlọ́run ẹni mímọ́ yóò sì fi ara rẹ̀ hàn ní mímọ́ nípa òdodo rẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 5

Wo Àìsáyà 5:16 ni o tọ