Àìsáyà 5:2 BMY

2 Ó tu ilẹ̀ rẹ̀, ó ṣa òkúta ibẹ̀ kúròó sì gbin àyànfẹ́ àjàrà síi.Ó kọ́ ilé-ìṣọ́ sí inú un rẹ̀ó sì ṣe ìfúntí kan ṣíbẹ̀ pẹ̀lú.Lẹ́yìn náà, ó ń retí èso àjàrà dáradára,ṣùgbọn èṣo búburú ni ó ti ibẹ̀ wá.

Ka pipe ipin Àìsáyà 5

Wo Àìsáyà 5:2 ni o tọ