Àìsáyà 5:20 BMY

20 Ègbé ni fún àwọn tí ń pe ibi ní rere, àti rere ní ibi,tí ń fi òkùnkùn ṣe ìmọ́lẹ̀ àti ìmọ́lẹ̀ ṣe òkunkun,tí ń fi ìkorò ṣe adùn àti adùn ṣe ìkorò.

Ka pipe ipin Àìsáyà 5

Wo Àìsáyà 5:20 ni o tọ