Àìsáyà 5:24 BMY

24 Nítorí náà, gẹ́gẹ́ bí ahọ́n iná ṣe ń jó àkékù koríko runàti bí koríko ṣe relẹ̀ wẹ̀sì nínú iná,bẹ́ẹ̀ ni egbò wọn yóò jẹràtí òdodo wọn yóò sì fẹ́ lọ bí eruku:nítorí pé wọ́n ti kọ òfin Olúwa àwọn ọmọ-ogun sílẹ̀wọ́n sì gan ọ̀rọ̀ Ẹni mímọ́ Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin Àìsáyà 5

Wo Àìsáyà 5:24 ni o tọ