Àìsáyà 5:27 BMY

27 Kò rẹ ẹnìkankan nínú wọn, tàbí kí ó kọṣẹ̀.Ẹnikẹ́ni ò tòògbé tàbí sùn;Ìgbànú ẹnìkankan ò dẹ̀ ní ìbàdí i rẹ̀,okùn sálúbàtà kan ò já.

Ka pipe ipin Àìsáyà 5

Wo Àìsáyà 5:27 ni o tọ