Àìsáyà 5:30 BMY

30 Ní ọjọ́ náà, wọn yóò hó lé e lórígẹ́gẹ́ bí i rírú omi òkun.Bí ènìyàn bá sì wo ilẹ̀,yóò rí òkùnkùn àti ìbànújẹ́;pẹ̀lúpẹ̀lú ìmọ́lẹ̀ yóò di òkùnkùn pẹ̀lú kùrukùru rẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 5

Wo Àìsáyà 5:30 ni o tọ