Àìsáyà 5:4 BMY

4 Kín ni ó kù tí n ò bá tún ṣe sí ọgbà àjàrà mi.Ju èyí tí mo ti ṣe lọ?Nígbà tí mo ń wá èso dáradára,èéṣe tí ó fi ṣo kíkan?

Ka pipe ipin Àìsáyà 5

Wo Àìsáyà 5:4 ni o tọ