Àìsáyà 50:6 BMY

6 Mo sí ẹ̀yìn mi sílẹ̀ fún àwọn tí ó ń nà mí,àti ẹ̀rẹ̀kẹ́ mi fún àwọn tí ń fa irúngbọ̀n mi;Èmi kò fi ojú mi pamọ́kúrò lọ́wọ́ ẹlẹ́yà àti ìyọsùtì sí.

Ka pipe ipin Àìsáyà 50

Wo Àìsáyà 50:6 ni o tọ