Àìsáyà 50:9 BMY

9 Olúwa àwọn ọmọ-ogun ni ó ń ràn mí lọ́wọ́.Ta ni ẹni náà tí yóò dámí lẹ́bi?Gbogbo wọn yóò gbó bí aṣọ;kòkòrò ni yóò sì mú wọn jẹ.

Ka pipe ipin Àìsáyà 50

Wo Àìsáyà 50:9 ni o tọ