12 Ṣùgbọ́n ẹ̀yin kì yóò yára kúròtàbí kí ẹ ṣáré lọ;nítorí Olúwa ni yóò ṣíwájúu yín lọ,Ọlọ́run Ísírẹ́lì ni yóò sì ṣe ààbò lẹ́yìn ín yín.
13 Kíyèsí i, ìránṣẹ́ mi yóò hùwà ọlọgbọ́n;òun ni a ó gbé ṣókè tí a ó sì gbégaa ó sì gbé e lékè gidigidi.
14 Gẹ́gẹ́ bí a ti rí ọ̀pọ̀lọpọ̀ tí wọ́n ń bọlá fún un—ìwò ojú rẹ ni a ti bà jẹ́ kọjá ti ẹnìkẹ́ni àti ìrísí rẹ̀ ní a ti bàjẹ́ kọjá ohun tí ènìyàn ń fẹ́
15 bẹ́ẹ̀ ni yóò ṣe bomirin àwọn orílẹ̀ èdè ká,àwọn ọba yóò sì pa ẹnu wọn mọ́ nítoríi rẹ̀.Nítorí ohun tí a kò sọ fún wọn, wọn yóò rí i,àti ohun tí wọn kò tí ì gbọ́, ni yóò sì yé wọn.