Àìsáyà 52:8 BMY

8 Tẹ́tísílẹ̀! Àwọn olùṣọ́ rẹ gbé ohùn wọn ṣókèwọ́n kígbe papọ̀ fún ayọ̀.Nígbà tí Olúwa padà sí Ṣíhónì,wọn yóò rí i pẹ̀lú ojúu wọn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 52

Wo Àìsáyà 52:8 ni o tọ