Àìsáyà 53:12 BMY

12 Nítorí náà èmi yóò fún un ní ìpín pẹ̀lú àwọn ẹni ńláòun yóò sì pín ìkógun pẹ̀lú àwọn alágbára,nítorí pé òun jọ̀wọ́ ẹ̀míi rẹ̀ fún ikú,tí a sì kà á mọ́ àwọn alárèékọjáNítorí ó ru ẹ̀ṣẹ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀,ó sì ṣe ìlàjà fún àwọn alárèékọjá.

Ka pipe ipin Àìsáyà 53

Wo Àìsáyà 53:12 ni o tọ