Àìsáyà 53:2 BMY

2 Òun dàgbà ṣókè níwájúu rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àṣẹ̀ṣẹ̀yọ èhù,àti gẹ́gẹ́ bí i gbòngbo tí ó jáde láti inú ìyàngbẹ ilẹ̀.Òun kò ní ẹwà tàbí ògo láti fàwá sọ́dọ̀ ara rẹ̀,kò sí ohun kankan nínú àbùdá rẹ̀tí ó fi yẹ kí a ṣàfẹ́ríi rẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 53

Wo Àìsáyà 53:2 ni o tọ