Àìsáyà 54:17 BMY

17 Kò sí ohun ìjà tí a ṣe sí ọ tí yóò ṣe nǹkan,ìwọ yóò já ahọ́nkáhọ́n tó bá fẹ̀ṣùn kàn ọ́ kulẹ̀.Èyí ni ogún àwọn ìránṣẹ́ Olúwa,èyí sì ni ìdáláre wọn láti ọ̀dọ̀ mi,”ni Olúwa wí.

Ka pipe ipin Àìsáyà 54

Wo Àìsáyà 54:17 ni o tọ