Àìsáyà 54:5 BMY

5 Nítorí Ẹlẹ́dáà rẹ ni ọkọ rẹ Olúwa àwọn ọmọ-ogun ni orúkọ rẹ̀Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì ni Olùràpadà rẹ;a sì pè é ní Ọlọ́run gbogbo ayé.

Ka pipe ipin Àìsáyà 54

Wo Àìsáyà 54:5 ni o tọ