Àìsáyà 56:10 BMY

10 Àwọn olùṣọ́ Ísírẹ́lì fọ́jú,gbogbo wọn ṣe aláìní ìmọ̀;Gbogbo wọn jẹ́ adití ajá,wọn kò lè gbó;wọ́n sùn sílẹ̀ wọ́n ń lálàá,wọ́n fẹ́ràn láti máa sùn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 56

Wo Àìsáyà 56:10 ni o tọ