1 Olódodo ṣègbékò sí ẹnìkan tí ó rò ó lọ́kàn ara rẹ̀;a mú àwọn ẹni mímọ́ lọ,kò sì sí ẹni tó yépé a ti mú àwọn olódodo lọláti yọ wọ́n kúrò nínú ibi.
2 Gbogbo àwọn tí ń rìn déédééń wọ inú àlàáfíà;wọ́n rí ìsinmi bí wọ́n ti ń sùn lókùú.
3 “Ṣùgbọ́n ìwọ wá níhìnín, ìwọ ọmọ àjẹ́ yìí,ìwọ ìran panṣágà àti aṣẹ́wó!
4 Ta ni ó fi ń ṣẹlẹ́yà?Ta ni o ń yọ ṣùtì sítí o sì yọ ahọ́n síta?Ẹ̀yin kì í haá ṣe ọlọ̀tẹ̀ ènìyàn bí,àti ìràn àwọn òpùrọ́?