1 Olódodo ṣègbékò sí ẹnìkan tí ó rò ó lọ́kàn ara rẹ̀;a mú àwọn ẹni mímọ́ lọ,kò sì sí ẹni tó yépé a ti mú àwọn olódodo lọláti yọ wọ́n kúrò nínú ibi.
2 Gbogbo àwọn tí ń rìn déédééń wọ inú àlàáfíà;wọ́n rí ìsinmi bí wọ́n ti ń sùn lókùú.
3 “Ṣùgbọ́n ìwọ wá níhìnín, ìwọ ọmọ àjẹ́ yìí,ìwọ ìran panṣágà àti aṣẹ́wó!
4 Ta ni ó fi ń ṣẹlẹ́yà?Ta ni o ń yọ ṣùtì sítí o sì yọ ahọ́n síta?Ẹ̀yin kì í haá ṣe ọlọ̀tẹ̀ ènìyàn bí,àti ìràn àwọn òpùrọ́?
5 Ẹ gbinájẹ fún ìṣekúṣe láàrin igi óákùàti lábẹ́ gbogbo igi tí ń gbilẹ̀;ẹ fi àwọn ọmọ yín rúbọ nínú kòtò jínjìnàti lábẹ́ àwọn pàlàpálá òkúta.
6 Àwọn ère tí ó wà ní àárin òkúta dídánwọ̀n n nì, nínú kòtò jínjìn ni ìpín in yín;àwọn, àwọ̀n ni ìpín in yín.Bẹ́ẹ̀ ni, sí wọn ni ẹ ti ta ọrẹ ohun mímu yín sílẹ̀àti láti ta ọrẹ oníhóró.Nítorí àwọn nǹkan wọ̀nyí, ǹjẹ́ ó yẹkí n dáwọ́ dúró?