Àìsáyà 57:16 BMY

16 Èmi kì yóò fẹ̀ṣùn kan ni títí láé,tàbí kí n máa bínú ṣá á,nítorí nígbà náà ni ọkàn ọmọnìyàn yóòrẹ̀wẹ̀sì níwájú mièémí ọmọnìyàn tí mo ti dá.

Ka pipe ipin Àìsáyà 57

Wo Àìsáyà 57:16 ni o tọ