Àìsáyà 59:3 BMY

3 Nítorí ọwọ́ọ yín di aláìmọ́ fún ẹ̀jẹ̀,àti ìka ọwọ́ọ yín fún ẹ̀bi.Ètèe yín ń pa irọ́ púpọ̀,ahọ́n an yín sì ń ṣọ̀rọ̀ nǹkan ibi.

Ka pipe ipin Àìsáyà 59

Wo Àìsáyà 59:3 ni o tọ