Àìsáyà 6:2 BMY

2 Àwọn Ṣéráfù wà ní òkè rẹ̀, ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn ní ìyẹ́ mẹ́fà, wọ́n fi ìyẹ́ méjì bo ojú wọn, wọ́n fi méjì bo ẹṣẹ̀ wọn, wọ́n sí ń fi méjì fò.

Ka pipe ipin Àìsáyà 6

Wo Àìsáyà 6:2 ni o tọ