Àìsáyà 60:10 BMY

10 “Àwọn àjèjì yóò tún ògiriì rẹ mọàwọn ọba wọn yóò sì sìn ọ́.Bí ó tílẹ̀ jẹ́ pé ní ìbínú ni mo lù ọ́,ní àánú èmi yóò ṣe inú rere sí ọ.

Ka pipe ipin Àìsáyà 60

Wo Àìsáyà 60:10 ni o tọ