Àìsáyà 60:17 BMY

17 Dípò búróǹsì, èmi ó mú wúrà wá fún ọ,àti fàdákà dípò irun Dípò igi yóò mú búróńsì wá,àti irun dípò òkúta.Èmi yóò fi àlàáfíà ṣe gómínà rẹàti òdodo gẹ́gẹ́ bí alákòóso rẹ.

Ka pipe ipin Àìsáyà 60

Wo Àìsáyà 60:17 ni o tọ