Àìsáyà 60:20 BMY

20 Òòrùn rẹ kì yóò sì wọ̀ mọ́,àti òṣùpá rẹ kì yóò sì wọ òòkùn mọ́; Olúwa ni yóò jẹ́ ìmọ́lẹ̀ ayérayé rẹ,àti àwọn ọjọ́ arò rẹ yóò sì dópin.

Ka pipe ipin Àìsáyà 60

Wo Àìsáyà 60:20 ni o tọ