Àìsáyà 61:10 BMY

10 Èmi yọ̀ gidigidi nínú Olúwa;ọkàn mi yọ̀ nínú Ọlọ́run mi.Nítorí ó ti wọ̀ mí ní aṣọ ìgbàlàó sì ṣe mí lọ́ṣọ̀ọ́ nínú aṣọ òdodo;gẹ́gẹ́ bí ọkọ ìyàwó ti ṣe oríi rẹ̀ lọ́ṣọ̀ọ́ bí àlùfáà,àti bí ìyàwó ṣe ń ṣe ara rẹ̀ lọ́ṣọ̀ọ́ pẹ̀lú ohun ọ̀ṣọ́.

Ka pipe ipin Àìsáyà 61

Wo Àìsáyà 61:10 ni o tọ