Àìsáyà 64:10 BMY

10 Àwọn Ìlú Mímọ́ rẹ ti di aṣálẹ̀;Ṣíhónì pàápàá aṣálẹ̀ ni, Jérúsálẹ́mù ibi ìkọ̀sílẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 64

Wo Àìsáyà 64:10 ni o tọ