Àìsáyà 64:7 BMY

7 Ẹnikẹ́ni kò pe orúkọ rẹtàbí kí ó gbìyànjú láti dì ẹ́ mú;nítorí ìwọ ti fi ojú rẹ pamọ́ fún waó sì jẹ́ kí àwa ṣòfò dànù nítorí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa.

Ka pipe ipin Àìsáyà 64

Wo Àìsáyà 64:7 ni o tọ