Àìsáyà 66:1 BMY

1 Ohun tí Olúwa wí nìyìí:“Ọ̀run ni ìtẹ́ mi,ayé sì ni àpótí ìtìṣẹ mi,Níbo ni ilé tí ẹ ó kọ́ fún mi wà?Níbo ní ibi ìsinmi mi yóò gbé wà?

Ka pipe ipin Àìsáyà 66

Wo Àìsáyà 66:1 ni o tọ