Àìsáyà 66:16 BMY

16 Nítorí pẹ̀lú iná àti idàni Olúwa yóò ṣe ìdájọ́ lóríi gbogbo ènìyàn,àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni àwọn tí Olúwa yóò pa.

Ka pipe ipin Àìsáyà 66

Wo Àìsáyà 66:16 ni o tọ